Burukutu - Olamide

Letra de Burukutu - Olamide

INFORMACIÓN DEL SENCILLO:

​"Burukutu"​ es una canción interpretada por ​Olamide. 

Fecha de lanzamiento: 30 de octubre del año 2026. 

Traducción Español

Significado

Letra Burukutu - Olamide

The don, the deal is done
(Baddo, we wanna party!)
(Baddo, we wanna party!)

If I no dey for Miami
I go dey for Barcelona
If I no dey Barcelona
I go dey for New York City
And if I no dey New York City
I go dey L.A, California (California, eh)
Wọ́n ní wọ́n wá mi ní ìgboro
Èmi ọmọ Èkó tó ní choko
Yí bí sọ́mbọ̀ tà bí ròdò
Make nobody come dey give me zobo
Kpokpodikpo, kpodikpokpo (Skido)
Wọ́n ní obìnrin ọ̀gbọ̀dọ̀ fi ojú kan ọ̀rọ̀
Àgbà awo ni mí, no be òtòndò
From ògànbọ̀ wọ́n mọ̀ dé s'ọ̀ngò
If you no sabi the vibe, you no belong o
Àwòrò ṣá ṣá, no be kéré koro (Okay)
Ayé deep gan, o ní kòtò
When it's your turn, kó yá kó fún wọn ìntótó (Give dem)
Ìbo l'ówó wà, make we dey go (Let's go)
Ọya já mi tàn bí ti Òpóbò (Póbò)
Sáré dágborù go show you logo (Logo)
Ar'ẹsẹ̀ jà bàtà tó ní mòtò (Mòtò)
Èkó Miami, ó yẹ kí ẹ ti mọ̀
To da to da de and so many more
And we no dey fall for anyone
Ẹni tó bá bẹ̀ Amotekun, ẹ yín wọn (Enjoy your weekend)

Aṣímájú kutukutukutu (Hey), kí ló tú kú?
Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fún mi ní burukutu (Hey), kí ló tú kú?
Aṣímájú kutukutukutu (Hey), kí ló tú kú?
Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fún mi ní burukutu (Hey), kí ló tú kú?

Fọ'kẹ zobo, nigga, ta l'ọn má pè ọ?
Dem no fit tell me 'bout the finals like Mbappé o
Fuck a nigga, ṣé èmi wá jẹ ọmọ aṣé o
Do as I do, nigga, not do as I say o
The psycho e choke like I'm on drugs
Sòrò ló máa pa yín bí ti ẹni tó yẹ k'ara bomb
Fuck my past, I'm not going there
Enemies wọn máa jí yín gbé bí Ṣaworoide
Tó bá gẹ́ yín, mo ní kí ẹ lọ tọ́
You no dey in-form again like Samuel Eto'o (Jọ̀ọ́ o)
B'ọmọge rí mi, wọn a ní mo dùn o
We no fit to jẹ́ ti ìwọ, kò bá mọ̀ ọdù o
And I don't really give a fuck about anyone
Kò ní skingba fún àwọn daddy wọn
Ọmọ ẹni ò gbọdọ̀ ṣe'dì bẹ́bẹ̀rẹ̀
Ká lọ wọ ilẹ̀kẹ́ sí ìdí stripper

Aṣímájú kutukutukutu (Hey), kí ló tú kú?
Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fún mi ní burukutu (Hey), kí ló tú kú?
Aṣímájú kutukutukutu (Hey), kí ló tú kú?
Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fún mi ní burukutu (Hey), kí ló tú kú?

Euro, ṣe owo yẹn ti wọle?
Ah-ah, o ṣa mọ
Gazamista
Abdul, Surulere, FC, o pọ
Eyan Wizzy one-on-one, wọn de'bẹ, eh
Rotimi RudeBoi ma sun, ma sun, ma sun, ma sun, ma sun
Eskeez, Ikorodu oga, o ṣa mọ
We be on that new school shit, innit? Ha-ha
Chew your chewing gum, chop your vanilla
Chop life, la vida loca
Sepakwain, quarantine
O lemu palm wine
Anyebo
O crandebo
Haibo
O Grandezior
O Titanium
O Gitanium
O Godzilla
O Titanic
The deal is done
Calificar Canción
Sé el primero en votar

¿Quién escribió "BURUKUTU" de Olamide?

Olamide

¿Cuándo salió "BURUKUTU" de Olamide?

30 de octubre del año 2026

Comentarios

Inicia sesión para comentar

Todavía no hay comentarios. ¡Sé el primero!

Lee la letra completa de Burukutu interpretada por Olamide. Descubre el video musical, la información del sencillo y explora más letras, álbumes y colaboraciones del artista en QLETRAS.COM.

Entra a tu cuenta
Inicia sesión o crea tu cuenta para enviar letras y guardar tus favoritas
o con tu correo
¿Todavía no tienes cuenta? Créala aquí
Recuperar contraseña
Escribe tu correo y te enviaremos un enlace para crear una nueva contraseña
¿Ya lo recordaste? Inicia sesión
Crea tu cuenta
Únete para enviar letras y guardar tus canciones favoritas
¿Ya tienes cuenta? Inicia sesión